Ọ` RẸ´ ṢÍṢE GẸ´ GẸ´ BÍI KÓKÓ O. ` RO. ` NÍNÚ EWÌ ADÉBÍMPÉ Ọ` JẸ´ DÒKUN TÍ ADÉBÁYỌ` FÁLÉTÍ KO
Keywords:
Ojú àmúwayé Yorùba, À?à Yorùbá, Ọ` rẹ´ ?í?e, Ewì Adébáyo. ` Fálétí, TíQ´ rì ìfojú-às. à ìbíle. `-woAbstract
Ọ‘ pọ‘ lo. po. ‘ àwọn onímọ‘ ló ti fi ọlọ´kan-ò-jọ‘ kan tíọ´rì wo kókó i?ẹ´ tí Adébáyọ‘ Fálétí fi ewì Adébímpé Ọ‘ jẹ´ dòkun rán sí àwùjọ. Fún ìdí èyí, èróńgbà wa nínú i?ẹ´ yìí ní láti wo ipa ọ‘ rẹ´ ?í?e gẹ´gẹ´ bíi kókó tí Adébáyọ‘ Fálétí ń fi ewì Adébímpé Ọ‘ jẹ´ dòkun rán sí àwùjọ. Ìtàn inú èwì náà ni à ó ?àmúlò láti fi bí à?à Yorùbá nípa ìgbàgbọ´ wọn nínú ọ‘ rẹ´ ?í?e hàn, ìpalára tí ìgbàgbọ´ ?in?in nínú ọ‘ rẹ´ ?í?e ń kóbá àwùjọ àti ènìyàn inú rẹ‘ . Tíọ´rì ìfojú-à?à-ìbílẹ‘ -wò tó ?àfihàn àwọn à?à tó súyọ nínú i?ẹ´ àláwòmọ´ lítíré?ọ‘ , tó sì ń ?àfihàn ewu àti àkóbá tí à?à náà n ?e fún àwùjọ àti àwọn ènìyàn inú rẹ‘ ni tío. ´rì tí ó s. e we.´ kún fún ìtúpale.‘ pépà yìí.
Downloads
Published
2026-06-18
Issue
Section
Articles